Abundance is a prophetic prayer song.
It has blessed many soul, lives, destiny and is still blessing.

Alábùdá ògo
Alámòlé ògo
Òpò nígbà òwón gógó

Òdá ohun rere kò ni dámi
Ohun rere yio rorùn ni sise
Nipa agbára to ròjò manna láginjù
Yio dùn, yio po, yio to fun mi

I will live in surplus
I will have abundance
Ma re oyin, maa la oyin
In exceedingly abundantly
Nire yio ma jé temi
Àká mi a Kun, àkúnwó sile
Devine insurance a gbémi to
Òfò ò ni semí pèlú gbogbo Eni fémi
Yio dùn yio po yio to fun mi
Mo ti the kòtó mole
Mo ti te àìní pa
Àlàjá to fàwòn ya ti bámi lálejò
All my needs are met
Ànító ànímó àníkún ire
Àpòtó ànísékù ire gbogbo
Onílé káyà káyó ló so bee
Òbánirìn kíyà Eni tán lo pàse

CHORUS

האזינו לאחרונה על ידי

0 הערות
    לא נמצאו הערות

:: / ::
::
/ ::

תוֹר