• 87
  • 2
  • 0
  • 4
  • 0

A song of thanksgiving and honor...it a song that gives reason for our living.
#

Jesus
Halleluyah..
My God is so good,he is so good to me.
I am in sanctuary,
Not in mortuary,I am happy to praise the Lord x2.
So I can shout hallelujah x3
Praise the Lord.
Solo 1: Majesty,glorious, Lord you are king x2
Me nene nambaka
Ma so Ina, hallelujah
am a winner.
Repeat chourse: I am in sanctuary...
Adlip:Oromo ni se faya gbe,
Obani mule mama dani
Atofarati mama yeyin,
Mogbe o ga ooo x4
Ese gan ni x4
Oluwa awon Oluwa o
Ese gan ni
Olorun awon Oluwa
Ese gan ni,
mowo waju Mori oo,mo we yin mori ooo X2
Lowo o tun mori oo.
Motun wosi Mori oo.
Nibi gbogbo ni gba gbogbo x2 mori o ooo X2
Arugbo o Mo Mari OO.
Moro were ninu aye mi
Mowa ninu kiye ninu iboji, Mo layo moyin Oluwa x2
E wo ohun ti Jesu se laye mi OO ojo mi loju, Oro ti se kose ni tole se,Victory last,I will praise you God.
Bridge:your highest I worship your name,your highest I praise your name,your highest I will worship your name,you are so good baba x2 .
Baba to weri Omo mo..dake dake OO x3 you are so good,
Olorun mi, oluranlowo Aye mi x2, Oba togberu mi nibi to ti wuwo..
O gberu mi ooooooo,
Ose ooo bami x2,ose ooo baba,
Oba to mu Ko sese x2
Ara ojo totipe ni, Anu Oluwa ti gbe jade, Ara ojo to ti Pepe Pepe x2
Ko ma pade ro tojo Ori mi,
Oti fanu gbe Jade OO.
Alanu Aye mi.. oluranlowo Aye mi, oluranlowo Ali ilenikan Ose..baba ah,ose Omo,emi mimo Moki OO oku ise. Ese x8
Ti Aye mi OO. Ni UN ooo magbe oga oo.nitoripe momo rere, Ni Tori pe, Momo ore to se ninu aye mi.
Ara nla leleyi,Ara ojo TI pe...

हाल ही में सुने

0 टिप्पणियाँ
    कोई टिप्पणी नहीं मिली

:: / ::
::
/ ::

कतार