Bukunmi Babarinsa ft Harjovy Gba Isakoso.mp3

  • 15
  • 2
  • 0
  • 6
  • 0
  • 0

“Pray for the peace of Jerusalem: "May those who love you be secure.“
Gba Isakoso is a song birth out of the desire and longing to see a new Nigeria, void of chaos and filled wither peace.

Lyrics

Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele ooo
Pipele,Pipele lo n pele o
Kaka k’ewe agbon de
Pipele lo n pele
Kaka k’oro iya aje,
O fi gbogbo omo re b’obirin
Kaka k’ewe agbon de
Pipele, Pipele lo n pele o

Ye, Oluorun o
Dide wa ran wa l’owo o
Gbo ohun ebe wa, ni Naijiria yi o
Olododo o si mo, won s’aye di je ki n je
Igunnugun yan ni je, Akala yan ni je, o lo o
Ye, Oluorun , Eledumare, wa ko wa yo

A n be o, Oluwa, dide ko gba Isakoso
Yi igba buburu pada si rere fun wa
Ounje to won, so won d’opo fun wa
Mekunnu n jiya, Eledumare wa ko wa yo
Rogbodiyan ile aye yi papoju, la se ke si o o
Lai si ese, ijiya o si o, Eledumare wa darijini

Pipele,Pipele lo n pele o e
Pipele,Pipele lo n pele o
Pipele,Pipele lo n pele si i, lojojumo o
Pipele,Pipele lo n pele o
Kaka k’ewe agbon de
Pipele lo n pele
Kaka k’oro iya aje, o fi gbogbo omo re b’obirin
Kaka k’ewe agbon de
Pipele, Pipele lo n pele o

::
/ ::

Queue

Clear