• 70
  • 2
  • 0
  • 1
  • 0

When God shows up on your case, be rest assured success is sure

*MO RI OLUWA*


*Call:* Oyoyo Oyoyo oo/3x (Welcome)_
*Resp:* Oyoyo Oyoyo oo/3x

*Call:* Eli Eli El-Sabaoth
Eli Eli El-Elyon/2x

*Resp:* Eli Eli El-Sabaoth
Eli Eli El-Elyon/2x
_You are the Lord of hosts_

*Call:* Muyi Masa Oyoyo/6x(we welcome you)
...Lord we welcome you...


*Resp:* Oyoyo Oyoyo oo/6x

*Call:* Mo r'Oluwa to joko nibi giga/
(I see the Lord seated in high places)

*Resp:* Mo r'Oluwa to joko nibi giga/2x

*Vocal:* Aso Igunwa re o kun 'nu tempili
(The train of His fill the temple)

*Vocal:* Agbagba merinlelogun won ke kabiyesile
(Twenty Four Elders casting down their crowns)

Mo r'Oluwa to joko nibi giga/2x

*Call:* Alagbada Ina - Ina Ina/3x }
Alagbada Ina oooo }/3x
(One with cloaks of fire)

*Resp:* Alagbada Ina - Ina Ina/3x }
Alagbada Ina oooo }/3x
__Alagbada Ina_
_Eru jeje leti okun pupa_
_Ekun oko Farao_
_Ina saaju Oluwa_
_O Jo gbogbo ota re run_
_Ina l'oju, Ina l'enu_
_Eli_
_Oninu funfun_
_Alaya funfun__

Mo r'Oluwa to joko nibi giga
_Beautiful beyond description_

Recently Listened by

0 comments
    No comments found

:: / ::
::
/ ::

Queue