• 64
  • 1
  • 0
  • 3
  • 0

And the Lord shall make me the head, and not the tail; and I shall be above only, and I shall not be beneath.... in Jesus name
Deut. 28 vs 13

OKE
Chorus: Oke Oke
Ni N’o Ma Looo
Oke Oke
Nibi Giga Giga
Oke Oke
Ni N’o Ma Loo O
Loruko Jesu
N’o Ma Gberu Si

Vocal: Ire Otun, Ire Osi
Ire Ni Gusu Ati Ni Ariwa
Ire Ni Ila Orun
Ati Ni Iwo Orun Oo
Loruko Jesu Ko Ma A Tele Mi
Loruko Jesu Ko Ma Ba Mi Gbe

Vocal: B’ope Titi O Akololo Mi
A Pe Baba
B’oti Wu K’orun Mu O
Sanma Dudu Yio Wa
Laipe Liajina La O Gbe Igba Ope Oo
Loruko Jesu M’o Ma Gberu Si



Call: Ori Ni N’o Ma Je, N’o Ni Je Iru Laye Ti Mo Wa Oo
Res: Loruko Jesu N’o Ma Gberu Si

Call: Ariki S’ore, A S’ore Kiri Ma Ni Jesu Mi O

Call: Adani Ma Gbagbe Ma Ni Jesu Mi Ooo

Call: Loruko Jesu N’o Ma Gberu Si

Recently Listened by

0 comments
    No comments found

:: / ::
::
/ ::

Queue